From: husseein selemani [kahingafr@yahoo.fr]To: rasyed@emirates.net.aeSubject: Mirza His life at a Glance in Yoruba/Nigeria Ijo Alatako Ahmadiyya ninu Esin Islam
Mirza Ghulam Qadiani Itan igbesi Aiye re niwonba soki
Awon itan Arikogbon nla to sele si-i ninu Igbesi Aiye re
Lati owo Dr Syed Rashid Ali
1839/40 Ni Mirza wa si Aiye lati ara Chiragh Bibi ati Ghulam Murtaza.
1846 - Mirza bere si-i ko eko Al-Qur’an ati awon hadiths pelu iran lowo Molvi
Fazl Ilahi
1849 - Molvi Fazal Ahmad ko ni awon orisirisi eko
1852 / 1853 - Mirza so yigi re akoko pelu Hurmat Bibi alias Phajje di
Maan Latara yigi yi loti bimo meji, Sultan Ahmad ati Fazal Ahmad
1857 / 58 - Gul Ali Shah ko-o ni eko awon ofin ijinle ti nwon fi nso ede Larubawa
1857 Ni ibere ija ominira ti a mo si ote awon India
- Latile fira re han gegebi omo odo rere ti nsotito pelu olowo ori re iyen
Ijoba British, baba Mirza bun ijoba British ni aadota awon agesi jagun
latile fi ba awon musulumi ja.
- Mirza Ghillare Qadir, egan Mirza ti-i se akobi baba Mirza
eniti o je ikan ninu Akogun ipin kerindilaadota labe ogagun
Nicholson, pa pupo ninu awon omo ogun Islam fun ominira legbe
Sialkot.
1864 - Mirza sa kuro nile baba re lehin igbati o gba owo isimi lenu ise ti baba
re tosi na ni inakuna, ina apa.
1864-68 - Mirza dari ipo akowe agba ni ile ejo Sialkot
- Mirza losi idanuwo awon amofin nibi toti fidi remi.
- Mirza yan Alfa ijo khrist kan ni ore ayo, eiti o gbe nkan pataki se lehin
naa
1868 - Ijoba England yan igbimo kan lati rori si awon ona ti nwon yio gba lati
yo emi ijagu soju ona Olohun Kuro lokan awo musulumi
- Mirza fi ipo akowe agba sile o fi wa si Qadian
- O firare han gegebi oniwasi iberu ati ipaya Olohun
1870 - Ababo ijoko igbimo oba fun awon agbenuso ijoba Briish re : « A laye
lori bi ijoba Britain se de ilu India »
Abajade igbimo naa nso wipe ki nwon o yan iranse Apostolique kan ki
o le pa emi jihad re kuro lokan awo musulumi.
1871 - Mirza Ghulan ni nwon yan sipo iranse Apostolique naa
1877 - Awon alase ipo yi fi esun odaran arufin kan Mirza
1879 - Mirza Ghulan perare ni ayanfe Olohun eniti Olohun ran nise si
gbogbo mutumuwa latile salaye ododo Esin Islam fun won
- Mirza Ghulam kede wipe owon yio pin iwe « Braheen-e-
Ahmadiyya » ka kiri, iwe ti owo yi o te ni aadota ipele.
- Mirza Ghulam kede tora iranlowo owo, osi gba awon agbatele latile fi gbe
Braheen-e-Ahmadiyya jade.
1879-84 - Mirza Ghulam pin ipele merin ninu iwe « Braheen-e- Ahmadiyya »
ka kiri 1884 - Mirza Ghulam da iwe « Braheen-e-Ahmadiyya » duro ni kiko.
- Laarin odun marundilogbon Mirza Ghulam te iwe bi ogorin
- Mirza npe iwe re « Braheen-e-Ahmadiyya » ni isipaya abi iwe ti Olohun fi
ranse si awon eru re
- Mirza Ghulam nperare ni oniwasu ipaya Olohun lododo (Mujaddid dine)
oluso esin dotun
- Mirza Ghulam so yigi re keji pelu Shah jehan Bergum, omobirin Nasir Nawal,
eniti o bimo meta fun-un awon naare
1- Mirza Bashiruddin Mehmood (Arode keji to si tun je baba Tahir, Arole to wa lori oye nississinyi)
2- Mirza Bashir Ahmad (eniti o ko iwe Seeratul-Mahdi)
3- Mirza Sharif Ahmad
- Nigbati Mirza Ghulam fi nso yigi keji o jewo loju gbogbo eniyan wipe oko
towun ko sise mo
O sadura wipe Olohun fun isa oko tuwun lokun kole ma gbe
O so wipe Olohun fi isipaya kan fi rase si owun ki owun Sewe kan ti yio je ara
tuwun ma gbe
- Latara awon ilana ti Olohun juwe fun-un, o sewe ale kan ti
npeni « TIRYAQ-e-ILAHI » eyiti ewe pataki towa ninu re nigbo ninu
(OPIUM)
- Mirza Ghulam toro lodo awon eniyan wipe ki nwon o bura wipe awon gba
owun gbo ni ojise
- Mirza Ghulam ntoro peki Mohamadi Begun ran owun lowo lati so yigi keta
ohun to npeni isipya lati odo Olohun ati pe gbogbo eyito wun ko je niu isoro ti
yio fe kodi towun lati fe omobirin yi yio ko igbesi Aiye mobiri naa ati enito ba
fee sinu idatmu ati ifunpinpin
1888 - Mirza Ghulam so setigbo eniyan wipe : « Kosi ona imole kan fun awon
eniyan lati mo ododo towun yato si iro towun bi ki-i ba se ona iranse ati
isipaya towun angan » (Ana-e-e Kamalate Islam, Roohani khazain ipele
Karun oju ewe 288 lati owo Mirza Ghulam)
- Mirza Ghulam ko ipahinkeke inira ba akofe iyawo re ati awon omo re nitori ki
nwon le ra-an lowo lati fe Bergum atipe bi nwon ko ba lowo si-i Begum koni
se fe fun-un-
1891 - Mirza Ghulam nperare ni Messiah, o si npe Messiah toto niro O npe
awon ti nwon jaro re ni opuro
- Mirza Ghulam nperare ni Mariam
- Mirza Ghulam tun nperare ni emi mimo ti Angel fe si Mariam lara to fi
loyun
- Mirza Ghulam nperare ni Issa (Jesus) lehin igbati o se osu mewa ninu
ara re, nigbati o je wipe owun nikan naa ni nperare ni Mariam lo tun
perare ni Issa (Jesus)
O so bayi wipe : « Bayi ni emi di Jesus omo Mariam » (Kishtee Nooh, Roohai
Khazain ewo oju ewe 87 si 89)
1891 - O da ijo Ahmadiyya sile ninu Esin Islam
- Mohammadi Begum so yigi pelu Mirza Sultan Baig
1892 - Ni isotan, lakotan
- Mirza ko akofe iyawo re sile
- Mirza ko omo re keji sile, o fi ogun du-u Akiyesi pataki : Akofe iyawo re je
ebi Mohammadi Begun
1893 - Abdullah khan Atham, alfa ijo Khrist kan lo pe Mirza ni ipade iforo jomitoro
oro kan lori alaye ododo Esin Islam
- Mirza so bayi : « Gbogbo awon eiyan ni nwon gbamigbo pelu awon oro mi
yato si awo omo pansaga ti Olohun ti di okan nwon » (Aina-e- kamalate
Islam, Roohani Khazain vol. R ; 548) E gbayi yewo : Awo akobi omo re ti
Mirza Ghulam so yigi iya nwon ti nje akofe iyawo re, awon omo ke ko gba
baba nwon Mirza Ghulam ni Messia !
Féb-1893 - O bere si ni se ipolongo iforo jomitoro oro ti yio waye laari owu ati Atham
- Ete Abuku ati itiju to ga i Mirza Ghulam ri he ninu iforo jomitoro oro yi
ohun to fa kuro ninu Esin Islam pupo awon musulumi ti igbagbo won le.
22/5-5/6/1893 - A lako igba Mirza Ghulam tun kede wipe emi Olohun nso fun owun wipe
Atham yio hu ni 5 September 1894
O so bayi : « Ti isipaya ti Olohun fi ran mi yi ba jasi iro, faramo gbogbo ibawi
to ba tibe jade » mo gbodo di eni abuku, ki ateju mi dudu, ki nwo pami ni pipa
enito pokunso ku… Mo bura wipe Olohun yio se gbogbo ohun ti mo wi yen
lakotan pata pata Ile ati sama le ma yi sugbon oro Olohun ki-i yipada (Jang-
e-Muqqadas, Roohani Khazain vol 6 P. 293)
Avr 1894 - Atham tun nsemi laye pelu alafia lehin 5 september 1894, ohun to yapa si
isipaya ati iriran Mirza Ghulam Pupo pa Atham nipakupa, awo eni aïmo ni
nwon fara kasa re.
4/09/1896 - Ota rire : Mirza se awon epe kan sori awon omo erupe ti o bu o si dawon
sinu koto nla kan ko le jasi isoro nla ti yio fa iku Atham.
6/09/1894 - Awon elesin Khrist nsajoyo odun isegun ti Alfa nwon Abdullah. Atham segun
Mirza Ghulam, nwon si fi Islam se yeye leiti nsowipe awon ki Mirza ku orire,
awon gboriyin fun-un. Sibe-sibe Mirza tun nfese isipaya ati iriran re mule lori
iku Atham ati isoyigi Mohammadi Begum O nwipe : « Toba je wipe iro ni mo
pa, ki nku lojiji ki isipaya ati iriran ma se ri bee » (Anjame Atham)
1896 - O sekede isipaya yi : « Nwon si nbere bayi wipe toba jododo so wipe :
« Beei, mo foruko Olohun bura ododo ni, ti e kosi le di-i lati sele. Awa ni a so
yigi re fun-un-kosi eni to le yi oro mi pada » (Asmani Faisala)
27/07/1896 - Mirza Ghulam pa adapa iro mo awon iya baba ati iya Jesus wipe onisina
alagbere ni nwon je, atipe ninu eje nwon ni owun ti jogun re, nidi eyi lowun fi
faramo awo oni pansaga.
- Mirza Ghulam kowe ebe si ijoba Britain.
- Mirza Ghulam fi ebun ranse si obabirin Victoria nigbati nuruge ade
owo (fadaka)
1897 - Awon ile ise owo-ode fi esun arufin kan Mirza
- Awon fura si-i wipe o lowo inu iku Pandit Lekharam, awon iwe ejo kan
ti sile fun-un ati idalare re
- Mirza ko iwe ebe si igbakeji olori orilede Punjab to fi nsalaye fun-un
abi ran-an leti wipe :
- Eru, omodo to sotito pelu awon oba nwo ni awon baba baba Mirza
Ghulam je
- Atipe owu gangan Mirza omo odo awon Britain ni owun je
1898 - Latigba ewe re titi to fi di omo odun marun
1899 - dilaadorin ni Mirza Ghulam ti pinu lori atima fi gege ikowe re ati ahan
re yi awo musumuli lokan pada kuro loju ona inigbagbo ododo si
Olohun lo sibi ima ki ife awon English siwon lokan pelu ima emi jihad
kuro lokan awon asiwere musulumi
- Nwon fi esun odara kan-an nitoripe o te ofin ijoba mobe
1900 - Mirza pa ofin ijagun seju ona Olohun (Jihad) re
- Mirza pe awon omo ijo Ahmadiyya pawon lase pe ki nwon o ma
pe owun ni ojise nigbati ijoba nkaye awon eniyan ti nwon ngbelu
- Mirza nperare ni ojise
25/05/1900 - Mirza Ghulam kede wipe gbogbo awon ti ko gbawun ni ojise nwon
ntapa si ofin Olohun ati t’ojise Nidi eyi ina nibudesi nwon.
1901 - Ife Mohammadi Begum ku lokan Mirza tobee to fi nsala la. O tun gbe
ikede tuntu miran jade latile gbona ete miran tun irin re gbe, ona ti
Begum ko fi nile bo lowo re ni fife nitoripe awon ibere kan ti o to
telerawon lati odo Olohun wa ni.
1902 - Nigbehin, awon apakan musulumi mu ero kan jade latile fi fun
Mohammadi Begum nifokanbale. Jaafer Zitly lo kede sinu iwe iroyin
kan wipe : « Owun ri-i ninu ala towun wipe iyawo Mirza Ghulam di
iyawo towun ». Oro pesi je lenu Mirza, agara da-a tenu-tenu. Ow