a
dake bi oyaya ko so gbolohun kankan sori oro yi to fi ku ni odun 1908.
Mohammadi Begum gbele aiye pelu okore fun ogoji odun lehin iku
Mirza pelu alafia ati opolopo ore.
8 Nov 1902 - Mirza kede wipe : « Awon ito ka awon oro towun ki-i-se awon Hadiths
bikose awon Ayaths Al-Qur’an ati awo isipaya towun gangan, lafikun,
nigbamiran mo ma nka awo Hadiths ti ko ba tako awo isipaya mi
Eyitoku inu awon Hadiths, mo ma ndawon nu bi iwe tori » (Zamima
Nuzoole Maseeh, Rhoohani Khazain vol 19 P. 140)
1903 - Mirza ko Minarat-u-l-Maseeh silu Qadian, lehin odu mejila to
fi polongo arare ni Messia ti nwon nwi
1904 - Mirza nperare ni Khrishna Olohun awon Hundous
1905 - Mirza fi ami soju awon ala ite ti Olohun bukan, yonusi nilu Qadian.
1906 - Mirza jewo wipe arun opolo nda owu laanu, atogbe si nyo-o lenu
tobee to fi nto nigba ogorun lojumo kan, latigba toti perare ni Ayanfe
Olohun ti o ran nise ni odun 1879.
- Mirza gberare sepe niwaju Olohun laarin owun ati sepe yi sinu awon
iwe iroyin leiti nso bayi wipe ki Olohun Alagbara julo ki o pa opuro
ninu awon mejeji nigbati olododo yio semi lo pelu alafia ati opolopo
ore. Arun igbe yiya ati ebi abi aru ajakale i kio pa opuro laarin awon
mejeji nitoripe awon arun mejeji yi ntumo si ibawi Olohun fun eni to ba
ku iku nwon.
1907 - Mirza puro wipe Olohun pe owun ni Muhammad ati Ahmad, odun
merindilogbon ti rekoja lori re ninu iwe Braheen-e-Ahmadiyya
(Haqeeqatul-Wahi, Roohani Khazain vol 22 P. 502)
- Mirza Ghulam npa adapa iro wipe Olohun fun owun ni 300.000 ami
latifi jeri awon isipaya towun.
15 Mai 1907 - Mirza fan enu, sete leso wipe awon ayath Al-Qur’an ti Olohun sokale
latifi sapole Annabi Muhammad (SAW), tun sokele leekasi latifi sapole
owun Mirza naa
a- ese 7 ori 17
b- ese 55 ori 1
c- ese 9 ori 33
d- ese 53 ori 9
e- ese 17 ori 1
f- ese 3 ori 31
g- ese 48 ori 1
h- ese 73 ori 15
i- ese 73 ori 1
j- ese 107 ori 3
k- ese 36 ori 3
(Haqeeqat-u-l Wahi Roohani Khazain vol 22)
- Mirza nsoro enu ni dun wipe : Olohun ndaruko towun lehin oruko
gbogbo ojise kookan, o wipe : « owun ni Adam, owun ni Noe, owun
ni Abraham, owun ni Isaac, owu ni Jacob, owun ni David, owun ni
Issa omo Mariam, owun ni Mohammad (ki ike Olohun ma lo bawon)
Odun 1907 : Mirza pin ipele kaarun ninu iwe « Braheen-e-Ahmadiyya ka kiri.
Ninu awon oro itisiwaju to wa ninu abala iwe naa nipe : « Ni ipilese,
mo sadewun wipe ipele aadota ni maa fi ko-o. Sugbon nigbati owun
pa odo ti a fi kun marun to fi nje aadota ninu akosile re, oseku marun,
Mirza wipe emi ti mu adewun mi se pelukiko ipele karun yi »
- Mirza seto apeje latifio gbalejo olumojuto ile owo ati oro aje ilu
Punjab.
- Iku Mirza : Lojiji ni Mirza safenufa arun Cholera funrare. Abamo ati
itiju lo fi so edun okan re ikelin fu baba iyawo re wipe : « Mir Sahib !
« Mo fi enu ara mi fa arun ajakale Cholera » ko le so gbolohun kankan
mo ti iku fi mu-u lo.
- Mohammadi Begum gbe igbesi aiye irorun ati orire fun odun marun le
logbon lehin iku Mirza Ghulam.
- Molvi Samaullah Amratsari, semi pelu irorun ati orire fun ogoji odun
lehun iku Mirza Ghulam
1908 - Hakeem Nuruddin di arole alakoko
1914 - Hakeem Nuruddin subu lori esin o fi bee ku
- Mirza Basheeruddin Mehmood, omo Mirza Ghulam di arole keji
Dr Syed Rashid Ali P.O Box 11560 Dibba Al Fujairah U.A.E