|
From: husseein selemani [kahingafr@yahoo.fr]To: rasyed@emirates.net.aeSubject: Mirza His life at a Glance in Yoruba/Nigeria Ijo Alatako Ahmadiyya ninu Esin Islam Itan igbesi Aiye re niwonba soki Awon itan Arikogbon nla to sele si-i ninu Igbesi Aiye re Lati owo Dr Syed Rashid Ali 1839/40 Ni Mirza wa si Aiye lati ara Chiragh Bibi ati Ghulam Murtaza. 1846 - Mirza bere si-i ko eko Al-Qur’an ati awon hadiths pelu iran lowo Molvi Fazl Ilahi 1849 - Molvi Fazal Ahmad ko ni awon orisirisi eko 1852 / 1853 - Mirza so yigi re akoko pelu Hurmat Bibi alias Phajje di Maan Latara yigi yi loti bimo meji, Sultan Ahmad ati Fazal Ahmad 1857 / 58 - Gul Ali Shah ko-o ni eko awon ofin ijinle ti nwon fi nso ede Larubawa 1857 Ni ibere ija ominira ti a mo si ote awon India - Latile fira re han gegebi omo odo rere ti nsotito pelu olowo ori re iyen Ijoba British, baba Mirza bun ijoba British ni aadota awon agesi jagun latile fi ba awon musulumi ja. - Mirza Ghillare Qadir, egan Mirza ti-i se akobi baba Mirza eniti o je ikan ninu Akogun ipin kerindilaadota labe ogagun Nicholson, pa pupo ninu awon omo ogun Islam fun ominira legbe Sialkot. 1864 - Mirza sa kuro nile baba re lehin igbati o gba owo isimi lenu ise ti baba re tosi na ni inakuna, ina apa. 1864-68 - Mirza dari ipo akowe agba ni ile ejo Sialkot - Mirza losi idanuwo awon amofin nibi toti fidi remi. - Mirza yan Alfa ijo khrist kan ni ore ayo, eiti o gbe nkan pataki se lehin naa 1868 - Ijoba England yan igbimo kan lati rori si awon ona ti nwon yio gba lati yo emi ijagu soju ona Olohun Kuro lokan awo musulumi - Mirza fi ipo akowe agba sile o fi wa si Qadian - O firare han gegebi oniwasi iberu ati ipaya Olohun 1870 - Ababo ijoko igbimo oba fun awon agbenuso ijoba Briish re : « A laye lori bi ijoba Britain se de ilu India » Abajade igbimo naa nso wipe ki nwon o yan iranse Apostolique kan ki o le pa emi jihad re kuro lokan awo musulumi. 1871 - Mirza Ghulan ni nwon yan sipo iranse Apostolique naa 1877 - Awon alase ipo yi fi esun odaran arufin kan Mirza 1879 - Mirza Ghulan perare ni ayanfe Olohun eniti Olohun ran nise si gbogbo mutumuwa latile salaye ododo Esin Islam fun won - Mirza Ghulam kede wipe owon yio pin iwe « Braheen-e- Ahmadiyya » ka kiri, iwe ti owo yi o te ni aadota ipele. - Mirza Ghulam kede tora iranlowo owo, osi gba awon agbatele latile fi gbe Braheen-e-Ahmadiyya jade. 1879-84 - Mirza Ghulam pin ipele merin ninu iwe « Braheen-e- Ahmadiyya » ka kiri 1884 - Mirza Ghulam da iwe « Braheen-e-Ahmadiyya » duro ni kiko. - Laarin odun marundilogbon Mirza Ghulam te iwe bi ogorin - Mirza npe iwe re « Braheen-e-Ahmadiyya » ni isipaya abi iwe ti Olohun fi ranse si awon eru re - Mirza Ghulam nperare ni oniwasu ipaya Olohun lododo (Mujaddid dine) oluso esin dotun - Mirza Ghulam so yigi re keji pelu Shah jehan Bergum, omobirin Nasir Nawal, eniti o bimo meta fun-un awon naare 1- Mirza Bashiruddin Mehmood (Arode keji to si tun je baba Tahir, Arole to wa lori oye nississinyi) 2- Mirza Bashir Ahmad (eniti o ko iwe Seeratul-Mahdi) 3- Mirza Sharif Ahmad - Nigbati Mirza Ghulam fi nso yigi keji o jewo loju gbogbo eniyan wipe oko towun ko sise mo O sadura wipe Olohun fun isa oko tuwun lokun kole ma gbe O so wipe Olohun fi isipaya kan fi rase si owun ki owun Sewe kan ti yio je ara tuwun ma gbe - Latara awon ilana ti Olohun juwe fun-un, o sewe ale kan ti npeni « TIRYAQ-e-ILAHI » eyiti ewe pataki towa ninu re nigbo ninu (OPIUM) - Mirza Ghulam toro lodo awon eniyan wipe ki nwon o bura wipe awon gba owun gbo ni ojise - Mirza Ghulam ntoro peki Mohamadi Begun ran owun lowo lati so yigi keta ohun to npeni isipya lati odo Olohun ati pe gbogbo eyito wun ko je niu isoro ti yio fe kodi towun lati fe omobirin yi yio ko igbesi Aiye mobiri naa ati enito ba fee sinu idatmu ati ifunpinpin 1888 - Mirza Ghulam so setigbo eniyan wipe : « Kosi ona imole kan fun awon eniyan lati mo ododo towun yato si iro towun bi ki-i ba se ona iranse ati isipaya towun angan » (Ana-e-e Kamalate Islam, Roohani khazain ipele Karun oju ewe 288 lati owo Mirza Ghulam) - Mirza Ghulam ko ipahinkeke inira ba akofe iyawo re ati awon omo re nitori ki nwon le ra-an lowo lati fe Bergum atipe bi nwon ko ba lowo si-i Begum koni se fe fun-un- 1891 - Mirza Ghulam nperare ni Messiah, o si npe Messiah toto niro O npe awon ti nwon jaro re ni opuro - Mirza Ghulam nperare ni Mariam - Mirza Ghulam tun nperare ni emi mimo ti Angel fe si Mariam lara to fi loyun - Mirza Ghulam nperare ni Issa (Jesus) lehin igbati o se osu mewa ninu ara re, nigbati o je wipe owun nikan naa ni nperare ni Mariam lo tun perare ni Issa (Jesus) O so bayi wipe : « Bayi ni emi di Jesus omo Mariam » (Kishtee Nooh, Roohai Khazain ewo oju ewe 87 si 89) 1891 - O da ijo Ahmadiyya sile ninu Esin Islam - Mohammadi Begum so yigi pelu Mirza Sultan Baig 1892 - Ni isotan, lakotan - Mirza ko akofe iyawo re sile - Mirza ko omo re keji sile, o fi ogun du-u Akiyesi pataki : Akofe iyawo re je ebi Mohammadi Begun 1893 - Abdullah khan Atham, alfa ijo Khrist kan lo pe Mirza ni ipade iforo jomitoro oro kan lori alaye ododo Esin Islam - Mirza so bayi : « Gbogbo awon eiyan ni nwon gbamigbo pelu awon oro mi yato si awo omo pansaga ti Olohun ti di okan nwon » (Aina-e- kamalate Islam, Roohani Khazain vol. R ; 548) E gbayi yewo : Awo akobi omo re ti Mirza Ghulam so yigi iya nwon ti nje akofe iyawo re, awon omo ke ko gba baba nwon Mirza Ghulam ni Messia ! Féb-1893 - O bere si ni se ipolongo iforo jomitoro oro ti yio waye laari owu ati Atham - Ete Abuku ati itiju to ga i Mirza Ghulam ri he ninu iforo jomitoro oro yi ohun to fa kuro ninu Esin Islam pupo awon musulumi ti igbagbo won le. 22/5-5/6/1893 - A lako igba Mirza Ghulam tun kede wipe emi Olohun nso fun owun wipe Atham yio hu ni 5 September 1894 O so bayi : « Ti isipaya ti Olohun fi ran mi yi ba jasi iro, faramo gbogbo ibawi to ba tibe jade » mo gbodo di eni abuku, ki ateju mi dudu, ki nwo pami ni pipa enito pokunso ku… Mo bura wipe Olohun yio se gbogbo ohun ti mo wi yen lakotan pata pata Ile ati sama le ma yi sugbon oro Olohun ki-i yipada (Jang- e-Muqqadas, Roohani Khazain vol 6 P. 293) Avr 1894 - Atham tun nsemi laye pelu alafia lehin 5 september 1894, ohun to yapa si isipaya ati iriran Mirza Ghulam Pupo pa Atham nipakupa, awo eni aïmo ni nwon fara kasa re. 4/09/1896 - Ota rire : Mirza se awon epe kan sori awon omo erupe ti o bu o si dawon sinu koto nla kan ko le jasi isoro nla ti yio fa iku Atham. 6/09/1894 - Awon elesin Khrist nsajoyo odun isegun ti Alfa nwon Abdullah. Atham segun Mirza Ghulam, nwon si fi Islam se yeye leiti nsowipe awon ki Mirza ku orire, awon gboriyin fun-un. Sibe-sibe Mirza tun nfese isipaya ati iriran re mule lori iku Atham ati isoyigi Mohammadi Begum O nwipe : « Toba je wipe iro ni mo pa, ki nku lojiji ki isipaya ati iriran ma se ri bee » (Anjame Atham) 1896 - O sekede isipaya yi : « Nwon si nbere bayi wipe toba jododo so wipe : « Beei, mo foruko Olohun bura ododo ni, ti e kosi le di-i lati sele. Awa ni a so yigi re fun-un-kosi eni to le yi oro mi pada » (Asmani Faisala) 27/07/1896 - Mirza Ghulam pa adapa iro mo awon iya baba ati iya Jesus wipe onisina alagbere ni nwon je, atipe ninu eje nwon ni owun ti jogun re, nidi eyi lowun fi faramo awo oni pansaga. - Mirza Ghulam kowe ebe si ijoba Britain. - Mirza Ghulam fi ebun ranse si obabirin Victoria nigbati nuruge ade owo (fadaka) 1897 - Awon ile ise owo-ode fi esun arufin kan Mirza - Awon fura si-i wipe o lowo inu iku Pandit Lekharam, awon iwe ejo kan ti sile fun-un ati idalare re - Mirza ko iwe ebe si igbakeji olori orilede Punjab to fi nsalaye fun-un abi ran-an leti wipe : - Eru, omodo to sotito pelu awon oba nwo ni awon baba baba Mirza Ghulam je - Atipe owu gangan Mirza omo odo awon Britain ni owun je 1898 - Latigba ewe re titi to fi di omo odun marun 1899 - dilaadorin ni Mirza Ghulam ti pinu lori atima fi gege ikowe re ati ahan re yi awo musumuli lokan pada kuro loju ona inigbagbo ododo si Olohun lo sibi ima ki ife awon English siwon lokan pelu ima emi jihad kuro lokan awon asiwere musulumi - Nwon fi esun odara kan-an nitoripe o te ofin ijoba mobe 1900 - Mirza pa ofin ijagun seju ona Olohun (Jihad) re - Mirza pe awon omo ijo Ahmadiyya pawon lase pe ki nwon o ma pe owun ni ojise nigbati ijoba nkaye awon eniyan ti nwon ngbelu - Mirza nperare ni ojise 25/05/1900 - Mirza Ghulam kede wipe gbogbo awon ti ko gbawun ni ojise nwon ntapa si ofin Olohun ati t’ojise Nidi eyi ina nibudesi nwon. 1901 - Ife Mohammadi Begum ku lokan Mirza tobee to fi nsala la. O tun gbe ikede tuntu miran jade latile gbona ete miran tun irin re gbe, ona ti Begum ko fi nile bo lowo re ni fife nitoripe awon ibere kan ti o to telerawon lati odo Olohun wa ni. 1902 - Nigbehin, awon apakan musulumi mu ero kan jade latile fi fun Mohammadi Begum nifokanbale. Jaafer Zitly lo kede sinu iwe iroyin kan wipe : « Owun ri-i ninu ala towun wipe iyawo Mirza Ghulam di iyawo towun ». Oro pesi je lenu Mirza, agara da-a tenu-tenu. Owa dake bi oyaya ko so gbolohun kankan sori oro yi to fi ku ni odun 1908. Mohammadi Begum gbele aiye pelu okore fun ogoji odun lehin iku Mirza pelu alafia ati opolopo ore. 8 Nov 1902 - Mirza kede wipe : « Awon ito ka awon oro towun ki-i-se awon Hadiths bikose awon Ayaths Al-Qur’an ati awo isipaya towun gangan, lafikun, nigbamiran mo ma nka awo Hadiths ti ko ba tako awo isipaya mi Eyitoku inu awon Hadiths, mo ma ndawon nu bi iwe tori » (Zamima Nuzoole Maseeh, Rhoohani Khazain vol 19 P. 140) 1903 - Mirza ko Minarat-u-l-Maseeh silu Qadian, lehin odu mejila to fi polongo arare ni Messia ti nwon nwi 1904 - Mirza nperare ni Khrishna Olohun awon Hundous 1905 - Mirza fi ami soju awon ala ite ti Olohun bukan, yonusi nilu Qadian. 1906 - Mirza jewo wipe arun opolo nda owu laanu, atogbe si nyo-o lenu tobee to fi nto nigba ogorun lojumo kan, latigba toti perare ni Ayanfe Olohun ti o ran nise ni odun 1879. - Mirza gberare sepe niwaju Olohun laarin owun ati sepe yi sinu awon iwe iroyin leiti nso bayi wipe ki Olohun Alagbara julo ki o pa opuro ninu awon mejeji nigbati olododo yio semi lo pelu alafia ati opolopo ore. Arun igbe yiya ati ebi abi aru ajakale i kio pa opuro laarin awon mejeji nitoripe awon arun mejeji yi ntumo si ibawi Olohun fun eni to ba ku iku nwon. 1907 - Mirza puro wipe Olohun pe owun ni Muhammad ati Ahmad, odun merindilogbon ti rekoja lori re ninu iwe Braheen-e-Ahmadiyya (Haqeeqatul-Wahi, Roohani Khazain vol 22 P. 502) - Mirza Ghulam npa adapa iro wipe Olohun fun owun ni 300.000 ami latifi jeri awon isipaya towun. 15 Mai 1907 - Mirza fan enu, sete leso wipe awon ayath Al-Qur’an ti Olohun sokale latifi sapole Annabi Muhammad (SAW), tun sokele leekasi latifi sapole owun Mirza naa a- ese 7 ori 17 b- ese 55 ori 1 c- ese 9 ori 33 d- ese 53 ori 9 e- ese 17 ori 1 f- ese 3 ori 31 g- ese 48 ori 1 h- ese 73 ori 15 i- ese 73 ori 1 j- ese 107 ori 3 k- ese 36 ori 3 (Haqeeqat-u-l Wahi Roohani Khazain vol 22) - Mirza nsoro enu ni dun wipe : Olohun ndaruko towun lehin oruko gbogbo ojise kookan, o wipe : « owun ni Adam, owun ni Noe, owun ni Abraham, owun ni Isaac, owu ni Jacob, owun ni David, owun ni Issa omo Mariam, owun ni Mohammad (ki ike Olohun ma lo bawon) Odun 1907 : Mirza pin ipele kaarun ninu iwe « Braheen-e-Ahmadiyya ka kiri. Ninu awon oro itisiwaju to wa ninu abala iwe naa nipe : « Ni ipilese, mo sadewun wipe ipele aadota ni maa fi ko-o. Sugbon nigbati owun pa odo ti a fi kun marun to fi nje aadota ninu akosile re, oseku marun, Mirza wipe emi ti mu adewun mi se pelukiko ipele karun yi » - Mirza seto apeje latifio gbalejo olumojuto ile owo ati oro aje ilu Punjab. - Iku Mirza : Lojiji ni Mirza safenufa arun Cholera funrare. Abamo ati itiju lo fi so edun okan re ikelin fu baba iyawo re wipe : « Mir Sahib ! « Mo fi enu ara mi fa arun ajakale Cholera » ko le so gbolohun kankan mo ti iku fi mu-u lo. - Mohammadi Begum gbe igbesi aiye irorun ati orire fun odun marun le logbon lehin iku Mirza Ghulam. - Molvi Samaullah Amratsari, semi pelu irorun ati orire fun ogoji odun lehun iku Mirza Ghulam 1908 - Hakeem Nuruddin di arole alakoko 1914 - Hakeem Nuruddin subu lori esin o fi bee ku - Mirza Basheeruddin Mehmood, omo Mirza Ghulam di arole keji Dr Syed Rashid Ali P.O Box 11560 Dibba Al Fujairah U.A.E Fax : 97192442846 E-mail : rasyed@emirates.net.ae » تاريخ النشر: 25-11-2009 » تاريخ الحفظ: » شبكة ضد الإلحاد Anti Atheism |