Where is the Grave of Jesus

BISIMILLAHI AL-REHMAN AL-RAHEEM

NIBO NI SARE JESU WA?

 

 

Ibere fun awon Ahmadi

 

lati owo Dr. Rashid

 

Eyin ara Qadiani tabi Ahmadi !

Alafia fun eni ti o tele hidayah (onama) naa.

Mirza Gulam Ahmad Qadiani, Oludasile Ijo Ahmadiyya so pe!

"Oluwa ti fi han mi ninu ibanisoro pataki pe Maseeh omo Maria ti ku"' (Tauzeeh e Maram, Roohani Khazain vol. 3 p. 402)

"Atiso fun mi nipa sare Isa (ni Kashmir). Ati wipe a ti so fun mi lati inu Alkurani Mimo ati iranse simi nipa iku Jesu." (Roohani K'hazain vol. 18 p, 358, 361)

Nje eyi ni sare Jesu?

"Sare Jesu: 7/24) lo wa ni aarin pataki ninu esin Kristiani, adiitu kan to jo re ti pe bi ojo esin gan, o ti n sun mo ko niyanju bayi ti awon iko onimo alumoni ile lati (Oxford University) ti n gbiyanju lati fidire mule pe soosi Jerusalem ni sare Jesu wa. Leyin odun mewa, Martin Biddle ati iyawo re, Birthekje -Biddle. ti wu ile lati awon ikankan ti won lo ati awon eroja ikole aye atijo lori ile naa jade pelu okuta sare ti aye o de oni. Aaye yi ni won gba pe ile ti asin Jesu si, ero yi papa ko tii koju ayewo titi di asiko ti ayewo to daju bere si ni waye.

Ki ni a so si eleyi?

A bi Sare Jesu wa ni Kashmir?

 

Website miran ti a pe ni Sare Jesu? Laiti fi di e mule pe sare Jesu wa ni Kashmir. Boti leje pe oni website yii kope elesin kan ni oun, a mo ododo foju han nigba ti eni to ni website jewo ni apero Ahmadiya kan, Mirza Tahir, Khalifa Qadiani ko bayi pe;

 

"Levin igba to ja bo ni bi ti won kan mo lori agbelebu, Jesu de si Kashmir, nibi to gbe lo eyi to ku ninu igbesi aye re. O wasu fun awon Isireli agbegbe naa, O pada fe arabirin kan ti a mo si Mariyam, o si bi awon omo fun, beeni alaye yii, o ku ni eni odun ogofa (120years). Sare re wa ni agbegbe Mohala kan Yar ni agbegbe olu ilu Srinagar, Jammu ati Kashmir, ni apa oke India won pe ni Roza Bal ("Aye Sare Alaponle")

Arakunrin yii se afikun bayii;

"Akole yii ati oro inu re ki se dukia igbagbo eni kankan tabi ijo, beeni kii se ero enikan nipa kiikan Jesu mo agbelebu.

 

Okunrin na wa jewo pe ifaramo ijo ti o ti far a mo je

 

“Itiju ni fun enia ti o ni won bi oun sinu ijo Ahmadi ti ko de ri Pataki Imam Mahdi. To baje pe itumo ka bi mi si Ahmadi ni yii, inumidun won ko bimi bee sugbon moya si be ni”

 

(source: posting of 9/9/2000 on Lahore Ahmadiyya Message Board).

Nje Qadiani kan se atupale ohun ti Mirza Ghulam ko nipa agbegbe ti a sin Jesu si? O dami loju pe enikan yin ko ti se bee, ti e ba si ti se bee, gbogbo e irinse etanje nla ni tabi ipinnu lati ye kuro nibi ododo.

Ni bayi, e je kinso fun yin ohun ti mo ba pade nibi akosile Mirza Ghuknii. Eni ominira lati gba tabi koo, saa e jowo lopolopo ko je leyin igba ti e ba ti wadi avvon oro wonyi ni ojuse temi ni lati fi ododo mule, leyin naa o, o ku yin ku Allah

Ninu opolopo iwe re, Mirza Ghulani A Qadiani, mu aaye meta otooto fun sare Jesu. Ewo ni o bamu?

Asin Jesu si Al-khaleeli (Gulailee)

Ni odun 1891, Mirza ko idi iwe nla kan. Izala Auham to ni oju ewe toto 948. Ninu idi keji iwe yii. o ko lekun rere pelu alaye to ko idamu ba okan lati fi idi e mule pe won ko mu Jesu ni ooye (physically), sugbon a sokale lati ori agbelebu. o lo si ilu re Alkhalil, o ku a si sin sibe, O ko bayi.

"Otito ni eyi pe Meseeh lo si ilu abinibi re. O si ku sibe, kii se ododo pe ara kan naa ji dide pada..... verse 3 chapter 1 of Acts je eri nipa iku Jesu ni Khaleeli. Leyin iku yii, maseeh fi ara han awon omo leyin re ni ona iran (vision) fun ogoji ojo." (Tzala-e-Auham, Roohani khazain vol. 3p. 353-354).

Sare Jesu ni Qudus

 

A mo saa, odun meta leyin naa, Mirza yi aalo re pada Ninu iwe e miran, Atlmam-e-Hujjat (Roohani Khazain vol. 8), o gbi yanju lekan si lati fi mule pe Isa omo Maria (AS) ku. Ni ati se eleyi, o mu eri ikan ninu awon omoleyin re kan toje Arab, Molvi Mohammed Al-seedi, Al-saami wa. O ko bayi

 

"A ni lati gba eleyi pe Isa ku, a tip e papa pe sare Isa wa ni Syria, ni ifi idaniloju han siwaju si ni isale iwe yi, mo fi eri omo iyami, Ololufe mi ninu Allah, Molvi Mohammed al-Saeedi Trablisi Tripoli lo n gbe ni ile Syria, ni adugbo re sini sare Jesu wa (AS). Ti o ba sope iro ni sare naa, nigba naa, eniti eri wa lori e, ki o se alaye igba, ti iro yi sele. Ti o ba ri bee, a ko ni amo daju ni sare awon ojise, a si ni lati so pe gbogbo ile isinku je iro" (Atmam E Hujat, p. 18-19, Roohani Khazain vol. 8 p. 296-297, dated 1894).

Iwe kiko;

Iwe ti Molvi Mohammed Al-Saeedi Trabilis

« Nipa Imam Hazrat Maulana ati I in am u mi. Assalamo alaikun wa rehmatullah wa barakaafahu. Mo gba ladura pe ki Oluwa wo e san (mogba leta yii lati odo Shaeemi Saheeb nigba ti mo n se aisan). Ohunkohun ni pa sare a ti awon ikan miran ti o bere fun, mo n ko lekun rere, oun ni yii. “Isa ni Baitul-Ieyin, ogbon ibuso Iowa laarin Bait-ul lehin, ati Qudus, beeni sare Jesu alaihe assalam wa ni ile Qudus, o si wa di oni, a ko Soosi ile ijosin kan sori e. Soosi ile ijosin yi lo tobi ju. Ninu re sare Jesu wa, ninu Soosi ile ijosin yi kan naa ni sare Marayam olododo, wa. Sare awon mejeji yii wa lo tooto" (Atmam-ul Hujjat, Roohani Khazain vol. 8 p. 299).

 

O dabi enipe eleyi yanju oro naa ni odo Mirza Saeb. Jesu ku a si sin si al-Qudus.

Sare Jesu ni Kashmir : Ni odun kejo si igba yi, Mirza tun yi alo pada lekan si. Ni bayii o bere si ni pe ete eko re tuntun; A sin Jesu si Kashmir

 

"Eri daju pe Eisa rin irin ajo lo si Kashmir. Leyin na, Allah fun ni ominira ati ike, o gbe ile yii fun gba tope titi to fi ku. Beeni, aaye sare re si wa ni ilu Srinagar (sare Yus Asif)" (Af-Huda, 12 June, 1902m p. 109)

 

"Ati so fun mi nipa sare Jesu (ni Kashmir)" (Roohani khazain vol. 18 p. 358, 361)

 

"Sare Jesu wa ni kashmir." (Roohani khazain vol. 18 p. 320, Nuzool-e-Maseeh, printed in 1909, leyin iku mirza ni ate jade).

Ni ba yi a ni awon oro meta otooto lati owo Mirza Ghulam Ahinad Qadiani nipa sare Jesu. Ibere mi si awon Qadiani ni pe ewo ni ododo? Al-kalil tabi Qudus iabi Kashmir?

 

Ola fun gbogbo eni to ba tele imana

 

 

 

Anti Ahmadiyya Movement in Islam

 

Dr. SEYD RASHID ALI

P.O. BOX 11560

DIBBA Al FUJAIRAH, United Arab Emirates

Fax : 00971 9 2 442846

rayed@emirates.net.ae

http://alhafeez.org/rashid/

تاريخ الاضافة: 26-11-2009
طباعة