عرض المقال :False Beliefs
  الصفحة الرئيسية » مـقـالات الموقـــع » كشف البلية بفضح الأحمدية » Non - Arabic Articles » Yoruba

اسم المقال : False Beliefs
كاتب المقال: webmaster

IGBAGBO AIYEDERU TI MIRZA GHULAM A.QADIANA

Lati Owo

Lal Hussein Akhter

Igbagbo islam ati igbagbo ti Mirza Sahib ti ilu Qadiani yato si arawon gedegbe.lari le se atilehin fun ero

buruki yi, mirza sahib ninu ero re, se awon adada le lati owo re ninua won ikan to lidi tabi yato si oro quran

ati hadith, mirza sahib gbe oro relori ona muhadith ; mujadid ; maudini,maseeh, Muhammad Krishna, jai

singh, zilliy, burooziyati awon alosotele ko duro lori awon eleyi nikan ati wi pe nigbati ko le kora re ni ijanu, o

ni oun papa ni omo olorun.lehin igbana lo tun wa se ipinu to si pe ara re ni olorun ati wipe ninu agbara re ni

oun tri da orun ati aiye tuntun pelu dida aqwon iran enia.le hinwa igbana ni o tun wa se ape juwe omo re to

nbo gegebi olorun o si wa ki niwe wipe-

“omo mi , ti won ma bi , oma je eniti won ma mo dada tio si ma ni aseyori, osi maje isispaya ti akoko ati

igeyin, o si ma je afihan haq ati ijunilo bi igbati olorun ti sokale lati orun wa( iwe al bushra vol.2 pg. 21-24 )

eyi ni aiye deru igbagbo ti awon o0nimo ijilenipa islam ri ki won to se ofin lait pe mirza ni keferi,nissiyin, mi o

ni so ikan pupo ni ori awon oro won yi.kaka be , ma she afihan oro mirza sahib fun awon olukawe.

1.Mirza Sahib ko nipa ara re pe:

“Emi ni muhadith (itamma matul bushra p.79 roohani khazain vol.7 pg.298)

2. oni oun ni mujaddid (eni ti o tun ikan se) ni nu oro re bayi

“ Mo ti gba iroyin lati owo eniti akoleri wipe emi ni mujadid ti esin yin ati asiwaju re” (Durrre- sameen,Persia

P.22)

3. O tun se ikedev nipa mahdiniyat

“ Emi ni mahdi (Miyar-ul-akhyar p.11)

4. Otun ro ara re wipe oun ni won daruko ninu ay alukuran “ mubasshirun be rasooliu ya’ati min ba ‘adi

ismohu ahmad” o tun wa ko wipe “ ati wipe eni ti o ma wa maje ahmad ,lelyi de ti se afihan re geggbi

maseel nitori wipe Muhammad je oruko jalalai ati ahmad jamali pelu ahmad ati eisa gegebi itumo jamlai tun

mo si ikan kan na . Won so fun wa pe ikan kan wa ninu “ mubashiruu be rasooliu ya’ati min ba ‘adi ismohu

ahmad” sugbon anobi wa (saw) kikan se ahmad ni,mkan , ohun ni Muhamad pelu gegebi a lopo Muhammad

ati ahmad.sugon ni iwon ojo igbeyin gegbi a so tele, ahmad nikan to tun ni aridaju jesu ninu ara re ni

aran(izala Auham p.673, roohani khazain vcol.3 p.463)

Mirza Sahib ti so ninu awon roro to wa loke yi wipe anobi wa (saw) ki kan se ahmad nikan sugon

Muhammad pelu,gegebi alopo jalal ati jamal. O da bi eni wipe idi pataki tio fi ko awon areo woyin ni wipe, tio

ba ti ko ako daju ni bere wipe huzoor ki se ahmad,nigba yen opo muslumi ni o ni fe re. Sugbon ti eni yanb

bas e ayewo re dada, mirza sahib ti fi idajo re han wipe oun ni won so ninu aya ti a ko eyi tio fi han

gedeegbe pe asotele hazrat Eisa (AS) ninu surah saff ninu kuran ki se ti naobi Muhammad sugbon ti mirza

Qadiani!

5.Ninu iwe tiryatq-ul-quloob mirza sahib ko bayi pe:

“Emi ni maseeh-e-zamaan (Jesu), emi ni khaleem –e-khuda(Musa),emi ni Muhammad, emi ni ahmad

mujitaba”(Tiryatq-ul-quloob p.3 roohani Khazain Vol.15 p134)

6.Ninu ibo mi, ose lalye siwaju si:

“Olrun to se mi gegeboi afihan gbogbo ojise o de ti so mi ni gbogbo oruko won.Emi ni Adam, emi na ni seth,

noah,Abraham,Isaac, Ishmael, Jacob, joseph, moses, dawud, jeus ati afihan to to ninu oruko ojise nla, eyi

ja si wipe emi na ni Muhammad ati ahmad”(Haqeeqatul-ul-wahi p.72 Roohani Khazain vol.22 p.76)

7.Ninu iwe kanan, oko wipe:

“ Ko sim ojise kan towa si aiye ti won ko ni fi orure pe oun.gegbi olohun se so ninu Braheem-e-ahmadiyya,

emi nxi adam, noah,Abraham, Isaac, Jacob,Ishmael,moses,david,jesu omo moriam, Muhammad,gegbi

burooz.Gegebi olrun fi oruko awon ojise pemi ti o si pe mi “Jaree allah fee Hill Al Anbiya”, gegebi ojise

olorun ni arin awon ojise.eyi didan lati se afihan awon ojise yo ku ni ara mi ati wipe gbogbo iwa ati isesi

awon ojise yoku ni won ti fihan mi.

8. Lati tun fi ogo mujaddidiyat ati mahdidniyat ti re han, o ko nlelyi ni iwe wipe:

“Emi ni gba mi ni Adam,a bi nigba mi moses abi nigba mi Jacob.papa,emi ni Abraham, iran mi oni ounka”

(Braheem-e-Ahmadiyya,part 5, Durre-Sameen P.100 Roohani vol.21 P.133)

Eyin onkawe ! pelu gbogbo awon akole ti ako si oke yi,o daju gbangba pelu aya nini ti mirza sahib se lo

gbogbo oruko awon ojise olorun lori ara re top nde tun so wipe gbogbo ogo awon ojise olorun wa ninu oun .

A fi bi ki aso wipe ose atak si awon ojise , o nfi ara re pelu pe gbogbo ebun ti won fun gbogbo nojise ti je ti

oun mirza Sahib nikan.

9.Mirza Sahib tun so pelu aini tiju pe:

“emi ni adam ati pe papa Ahmad-e-mukhtaar mo ti won aso gbogbo awon eni momo gbogbo agbara ti won

gbe fun awon ojise ti je ti oun nikan bayi.(Durre-Sameen ,Persian P.163)

Eyi ahmadi Lahori, nitori ti olorun , adahun pelu ero ati ododo,nje itumo aro sd o ti mirza sahib pe ara re yi

jekaopo awon iwa mimo ojise , ko ti ede r ara re pe oun kare si awon ojise

10. Bakana lose so ninu aro so re wipe:

“ Bo ti le je wipe opolopo awon ojise lo tiwa si aiye ninu agbara, egbe kanana ni wa . (Durre-Sameen,

Persian P.163)

11.Pelu iyanu ,mirza sahib ko sa I so wipe ise iranse topun ti ko gbogbo awon ise awon ojise to ti koja papo,

otun so fun gbogbo aiye pe oun ni apo ti gbogbo awon ojise wa ninu re, o si ko bayi:

“Igbogbo awon ojise ji dide nigba ti mo de gbogbo awon ojise ni won sa pamo si abe aso mi.( Durre-Sameen

,Persian P.163)

Ma’az Allah min haazal hafwaaat. Ki olohun oba Allah ko so mi nibi isokuso yi.

12. Ninu ibo I o se iyan gan nipa ayeye re ninu gbolohun won yi:

“ni asoko yi olhun fe ki gbogbom ase awon ojise oltito ati alalponle ti won ti re koja, ko wa ninu enia kan

osoo, oni toun na si ni mi. (Braheem-e-Ahmadiyya, part 5, P.90 Roohani Khazain vol.21 P.117-118).

Eyi ara Lahori, e so fun mi nigbawo ni mirza sahib so naar re di adapo ase awon ojise olotito ati alalponle,

lehinna,kilo ku nile lati tun so wipe oun ju gbogbo awon ojise lo . ki e to fe si, eranti eniti owa ni iwaju yin.

13. Mirza Sahib so bayi:

ogba adam ti won ko se tan , pelu didde mi ni siyin, ti pari pelu ododo ati eso (Durre Samen,Urdu p.122)

eyin onkawe, e wo iwa ainitiju ti Mirza Sahib wu pelu sisos wipe ogba ola,olaju , ifomansin,ilosiwaju, atiu

idagbasoke to Hazrat Adam bere, wipe ko ti pari.sugbon ni gba ti oun de nisiyin, ogba na ti paripelu awon

orisirisi ododo ati eso.gegebi eni wipe disde re loje ki ise na ko le pari,ti won ko ba bi ,agbaiye yi koni si

niube ,oorun ati osupa kosi ni aye won ati awon irawo ti oyi orun ka , iler aiye koni si nibe,iran eniyan papa

kini waye, awon ojise k oni wa , al-kurani mimo ko ni sokale.

14. Ni kukuru,gbogbo ikan tio wa ni agbaiye ni ada n0itori mirza sahib gegebi o se so ninu oro re.”Law laa

ka, lamaa khalaqtul aflaaak(“Iwo mirza,ti ko ba si notiri re ni , mio ni da awon orun(Al-Bushra vol.2 P.112)

15. Ninu ibo mi, otun fi yewea , o ni:

“Kullo lak wa leamrik-gbgbo ikan mi tie ati ni abe ase re (Al-Bushra vol2 P127)

16. Otun ko bayi

“Olorun da adam, ode fun mi ni gbogbo ikan to fun adam,babagbogbo eda,o de fimi se aworan khatam-unnabiyeen

ati syed-ul-mursaleen (Khutba-e-lilhamiya P.167,Roohani Khazain vol 16.p.254)

17. O tun se alaye siwaju si:

“ati wipe niwon igba ti anobi Muhammad npa da bo,gege bi aya to so wipe “wa aakhareena minhum” (62:3)

ko le je oto ayafi ko je apere, nitorina , ise emi ti ojise nla ni lati yan eniyan fun rare ti o jo ni iwa

omoluabi,ikiya, anu fun ise eda ati ifikan weikan ti fun oruko oun ni re to je ahmad ati muhammamd lati le

je ki a gbo agboye wipe didie (mirza) je afihan gan ti ojise nla(Tohfa –e-holrowiya P.101 Roohani Khazain

vol.17 p.263)

18. Olorun ti rojoike to se fun ojise Muhammad le mi lori, ode se asepe ise . o de tun yi eda ati ore ofe re si

odo mi titi ti eda ti emi fi di ti e.nitori wipe gbogbo eni tio bafe wo inu ijo(ijo ahmadiyya) oni lqati wo inu ijo ti

egbe oluw a mi ati olori awon iranse .eleyi ni itumo aya “ wa aakhareem minhum(63:3 )” (Khutba-e-iihamiah

p171,Roohani Khazain vol.16 p258)

19. O tun gba agbara okun ,Muhammad mufleh o de se awon alaye yi :

“ Hazrat Maseeh mowood so wipe ale yi ti tun fun mi ni oruko kan si ti e ti gbo ri >mo sun die mo de gba

agbara okun yi “(Al-Bushra , vol.2 p.99). qawonm oro won yi se afihan gbangba pe mirza sahib so pe

afihan oruko oun ni “Muhammad mufleh” ati wipe oun da bi ojise nla ninu iwa , isesi, ikiya, ati anu fun

gbogbo awon ijo mirzaiyah oun da bi (sahabi-Alajose ) ojis e nla eyi ara lahori! nje e gba gbogbo awon

nkan won y i gbo?

20. Mirza Sahib tun so wipe :

“ Emi na ni mahdi ti ibn siren bere pe o wa aye kanan pelu abu bakr o de da lohun wipe ko fi abubakr sei

egbe kan, oun oun papap d aju awon ojise mi lo” (miyar-ul-Akhyar P.11)

21. Mirza asahib gba agbara okun : “Ema se fi oju abuku wo ipo mirza . awon ojis e ma nja gba nip[a asiko

re” (Al-Bushra vol .2 p. 109.

22. Lehin bibi omo kunrin re ati eniti oje alefa bayi nilu qadian , mirza Muhammad, awon nkan wonyi loje

iwuni lori tow afun mirza sahib nipa omo tuntun na:”

Eyin ojise alaponle! Isunmo yin ni ati fihanwa , ope kietod e ati pe ona jin jin ni etimbo” (Tiryaq-ul-Quloob

p.42, Roohani Khazain vol.15 p.219)

Eyuin omo jamaa lahori! Tet dahun ni gbolohun meji. Boya Agddi Nasheen ti asiko ti wayi tise ti Qadian

Mirza mahmud Ahmad ohun ni Fakhr-e –rusul awon ojise ti lae ponle abi tia kole ponle?Awon wo ninu ojise

ti ole fi asiko mirza sahib yangan? Ninu igbagbo re, tani m,irza sahib julom ninu awon ojise?

23 .Mirza Sahib kowe bayi:

 “Iwo (Eisa) omo maryam , fake mase sope Ghulam Ahmad gaju ohun lo! (Iwe dafe al-bala p.20,Roohani

Khazain vol.18 p.240)

24. Ni’ibomiran , otun ko bayi:

“Eyin alufa chriatiani! Mase so pe “rabbonal maseh-olowa wa ni maseeh”.wo loni , eni kan wa ninu yin ti

ogaju maseeh yen lo”(iwe dafe –al- bala p.20,roohani khazain vol.18 p.240)

25. Ni ede izala Auham ni oti sonkan tio gbagbo bayi pe

“Emi ni eni to wa nipa iro dunnu ni ibudo ojise Eisa pe ofi ese re le ibiti emi yio ti bani soro.(iwe izala –

elauham p.158, Roohani Khazain vol.3 p.180)

26. Otun selaye siwaju awon nkan tio gbagboyi: “Olorun Oba Allah ti ran ojise na ti ati seleri re ninu awujo

yi tio gajulo ninu agbara re ju eni ti eyinwalo.(iwe Haqeeqat-ul-wahi p.148,Roohani Khazain vol.22 P.152)

27. Nbinvu iwe kana otun ko pe

“Mobura pelu oruko enikan tio se pe oworw ni emi mi

Eyin omo leyin Mirza, Sahib! Tobajepe Mirza Sahib ba wa gege be Alukurani, nigbana kinide ti eyin ka Urdu,

English tabi Germani ti a koni Kurani? Eyin ti bagbe eko Mirza Sahib, Nigba toni pe ohun wa gege bi

Alukurani, lehina, oya aworan ara re, nibikibi ti o ba ti fe Alukurani tabi alaye re ni edekeole, sa fi aworan re

ranse lesekese.

38. Mirza Sahib fun so niwe re pe:

Ti enikan ba fi enukan ese me, emi a so fun enibe pe emini Hare-As wad (Okuta dudu ti ka’aba)” Albushra

Vol P.48).

Eleyei jasipe, bi ogbenina se sope ohun tidi Hare-e-Aswad, oti si ona fun awon omolehinre lati ma pan ese

rela nigba gbogbo. Sugbon eyin ti entele ogeni na. (Mirza Sahib), ore yin, eyin si malo pon ese rela ninu

saare (grave).

39.Ogbeni Mirza Sahib fun so pe:

“Ilu Qadi ani ti di iloe mimo, ki aown eyan mawo wasibe. Otidi ilu Makkah bayi” (Iwe Durre Sameen, Urdu

P.52).

Eyin omo Ahmadi, bayi, olori yin ti tayo ala. Se eleyi ni ogbon imo ti owuni lori ti oga yin Mirza mu wa fun yin.

Esi eti yin sile, esope ilu Qadiani ti di ilu alapanle nitoripe awon eyan ama wasibe nitorina otidi ilu Makka.

Nisinyi, eyuin ko ni layi losi Makka mo fun isin Hajj. Qadiani ti di ili Mecca ati pe Mirza Sahib ti di okuta Hajre-

Aswad. Nitorina, ewoye si oro rirun yi eyiti oda be ile egbin ti won ti new kanga sam-sam. Legbe saree oga

yin ni rekunmi kan ti ohe ti Dajjai. Nipa rakunmi yi, iwole wasi Qadiani lesekese nibikibi ni ilu Hindustan.

Beni, mase bagbe. Qadiani ni ibi kanna ti awon ojise yin ti won pe ni Mujaddid/Zilli/Buroozi. Ti gba agbara.

Beni, kokanwa boya ilu Qadiani tidi ilu Makka ka’abba, wahala tiyin ni. Sugbon tio ba dayin loju efun wa ni

idahun si ibere kan. Nigbati oga yin ti sope wiwo awon eyan silu Qadiani tiso be di Makka, nje nigba wo ni

ema lo da ka’abba si ilu New York ni America, London at Berlin ni Germani?

Awon oro ti Mirza Sahib sope ohun gbo lati odo Olorun.

40. “Wa maa aralnaaka ila Rahmat al Alameen” “Iwo Mirza, Awa ran gege bi annu fun gbogbo agbaye” (Iwe

Anjam-e-Atham P.78, Roohani Khazain Vol. 11 P.78).

41. “Daiyan il,a Allahe” ati sirajum Muneer, oruko meji ati oye meji ti a fun Anabi Muhammad (S.A.W)

ninu Alukurani, bakanna ni a fun emi na. (Iwe Arba’reen No. 2 P.5, Roohani Khazain Vol. 17

P.350).

42. “Emi ni Krishna fun awon ara Hindu (Lecture Sialkot P.33).

43. Kotosi enikan lati ba Brahimn Autar ja, iyen Mirza Sahib (Albushra Vol. 2 P. 116).

44. Igbese mi wa lori gegele Mosalasi nibiti ogaju (Iwe khutba-e-Iihamiyah P.35)

45. Opolopo aye ola lowasile lati orun sugbon aaye olatire ni agbekale si aaye to gaju.

46. Olorun tifun mi nkan na ti koti feni kan ri ni agbalaye (iwe Haqeeqat-ul-Wahi P.107, Roohani

Khazain Vol. 22 P.110).

Ein eyan! Gbogbo oro wonyi ati awon oruko wonyi ni agbefun Ogbeni Mirza Sahib. Oya ni lenu wipe enkan

soso ni oko won oye wonyi mora. Ogbeni na ti kowe lorisirisi beeni awon omo leyin re tun sope ninu Hadith,

ona meji ni ati daruko oga awon, ti won pe ni Maseeh Nasiri at enitiwon so asotele re.

Bawo ni ase malero wipe apapa awon ojise lori Muhammad, Ahmad, Issa, Musa, Ibrahim, Krishina,

Brahimin Autar, Jaisingh Bahadu ati bebe ni a kojopo to di Mirza Sahib.

50. Ogbeni Mirza Sahib tun sapejuwe iranse tire pe. Olorun oba nyin ohun osimbo lodo ohun ugbon

koje kamo boya Olorun de odo ohun otun so wipe olorun ba ohun so gbolohun bayi “Antaa Ismee

al’Alalaa- O! Iwo Mirza, iwo ni oremi to gajulo (iwe AlBushra Vol 2 P.116).

Ah! Haba, Krishan Qadani ji, Iwo na lole so iru oroyi, kiotodi pe iwo ma so iru eleyi jade, unje oha ro

nkan ti awon christiani ati Arya Samaji le so. Kini kati gbo wipe kiato bi Mirza Sahib, awon Muslim

komo orukonla ti Olorunje ati wipe Alukurani at Hadith ko fun wa ni apejuwe oruko nla na. Ogbeni

Mirza fe fi dawaloju wipe oruko nla na ti Oloru nje ni Ghulam Ahmad.

51. Oro miran ti Ogbeni Mirza tunsope ohun gbo lati odo Olorun ni eyi; ‘Anta Modinatulilm. Leyin pe iwo

Ogbeni Mirza nilu imo.

Oga wa, Anabi Mohammad loti sope: Ana Modinatul-Umwali Ali Baa bolia. Iyen ni pe emi ni ilu imo

lati pe Ali ni oju ona imo na. Sugbon Ogbeni Filu Qadiani Krishan sope ohun kana ni ilu imo.

Ogbeni Mirza se oro tire ni ki agba lodo do no tabi oro ti Hadith Anabi Muhammad?

52. Ogebi Mirza tun tesiwaju ninu oro re: “Inu hami ur Rahman” Emi ni odi Olorun (Iwe AlBushra Vol. 2

P.89).

Eyin ara! Ogbeni Mirza tunsope ohun ni odi Olorun, iru odtiri awon agbe nse si oko won lati fi dabo

bo oko won. Eleyi tumo siwipe eniti onranse si Ogbeni Mirza (Olorun) ko lagbara lati dabobo arare

atipe ole ni. Sugbon sa, awa mo wipe Olorun ti wa, Alaanu ni, Aladipele esan ni, Alagbara ni pelu.

53. Ogbeni Mirza Sahib ko dake, on ohun tun gba oro kan to sope, Mombo lodo re pelu awon nkan

oro. Emi ma se asise beni emi ma se dada. (Iwe AlBushra Vol. 2 P.79).

Eyin omo leyin Ahmadi! Iye ni pe Olorun ti onranse si Olori yin manse asise. Nje osegbolenu wipe

Olorun oba kansoso ati Olorun Oba ti omo kinga le se asise bi? Eleyi ti han pe Ogbeni Mirza Sahib

ti kosinu pampe asise ati ewon asise aigbagboye. Sugbon kise ejo ohun na bikise ejo iro tompa

tosope ohun amagba gbolohun iro lati odo Olorun.

55. Ogbeni Mirza Sahib tun wipe ohun gbo pe: “Emi yio se adura, emi agba awe, atipe emi alsun loru.

(Iwe AlBushra Vol. 2 P.79).

alukurani Alaponle so nipa Olorunb Allah pe: ‘La Takhozohu Senatun Walaa naum”. Olorun kitogbe

beni kisun. Sugbon Olorun ti Ogbeni Mirza Sahib amaji asitun ma sun. ose pataki ki awon

omolehun Ogbeni na se bakaye lati mo eyiti se otito yatosi iro.

56. Ogbeni Mirza Sahib kosinu iwe re ti ampe ni Haqeeqat-ul-Wahi. Emi ri Olorun gbaungba to daju,

mosi ko opolopo iwe pelu owo mi nipa orisirisi iriran timori. Pelu itumo bi awon nkan imori se ma

sele. Mosi gbe iwe na fun Olorun lati ju owo si. Laisi wahala rara, Olorun si ju owo siwe na pelu

gege (Pen) Olorun si fawabale, pelu suru nigbati onjuwolu iwe na, emi na si nsunkun wipe Olorun

le sikesege fun mi bayi, wipe Olorun le ssaponle min to bayi tofi je wipe gbogbo nkan kinkan timo

nfe ki Olorun bami towobo ni oma nse fun mi lai beju wehin rara, mokan taji lasiko yi ni. Lasiko yi ni

Ogbeni Abdullah Sanwari nfowo pami lese ninu yara mosalasi, nigbayi gan ni hantu jabo si ewu mi

ati fila Ogbeni Abdullah. Eyito yami lenu nipe asiko ti hantu (ink) jabo simi lewu ni gege (Pen) ha

iwe. Eleyi kole ye awon alaim

الصفحات [1] [ 2]
اضيف بواسطة :   admin       رتبته (   الادارة )
التقييم: 0 /5 ( 0 صوت )

تاريخ الاضافة: 26-11-2009

الزوار: 4325


المقالات المتشابهة
جديد قسم مـقـالات الموقـــع
القائمة الرئيسية
البحث
البحث في
القائمة البريدية

اشتراك

الغاء الاشتراك