okan, nitoripe yio ma se iyemieji pe boya alani ohun nla. Sugbon sa, awon ojogbon nikan ni oleye. Bakanna, Olorun le mu nkan jade nibi ti kotosifele.
Mo se alaye gbogbo ise;e yi fun Ogbeni Abdullah Sanwari ti ekun si njabo loju mi Ogbeni Abdullah
se ijeri si alayi, osi fi ewu mi pamo gege bi ike fun. (Iwe Haqeeqat-ul-Wahi P. 255, Roohani Khazain
Vol. 22 P.267).
Eleyi omo leyin Mirza! Alukurani Alaponle so wipe ‘Laisaa ka Misle Hee Shaiyun-Kosi nkankan ti
ale fiwe Olorun oba. Kosi afijo fun Olorun. Sugbon Ogbeni Mirza kotile wo oro Alukurani rara kioto
ma sope ohun ri Olorun loju koroju. Bawo ni enikan se feri eniti kosi Afiwa. Nitorina, kiatole gba
Ogbeni Mirza gbo oni lati fi apejuwe na hanwea ninu Alukuran ibere kan ti Ogbeni Mirza ni lati
dahun nipe nigbati ogbe iwe fun Olorun lati fowosiwe, se hantu (ink) at gege na, pelu ewu ati fila
Abdullah je awon nkan ti alefoju. To ba je be, oye ki Ogbeni Mirza Sahib jeki afojuiri awon iwe na
atipe ede won ni afiko atipe ede wo ni Olorun fijuwo si iwe na? Ati wipe kini awon nkan towa ninu
iwe iriran na.
Nigbati Olorun ti fowo siwe na, inje awon nkanna se tabi ko pada se? nje ni gbati gege ti Olorun lo
lati sign iwe na gbe hantu to poju, se owun Olorun ki hantu na ja tabi asiseni?
57. Ogbeni Mirza Sahib sowipe:
Mori ninu ala pe mo wa ninu Cotu (Court) Olorun ti mo aduro de ojo tiwo pemi fun. Mokan dede
gbo, iwo Mirza, se suru, ambo lati da e lohun. Lekan na mokan ri Olorun ti o joko sori agba gege
biu adajo. Legbe kan akowe kan wa to kowe fun Olorun, Olorun sigba iwe na osiso bere pe se
Ogbenio Mirza wa ni kotu? Lehin a mori pe aga kari wa egbe Olrun tikosi enikan lori aga na, Olorun
si sofuni pe kinjoko sari aga na. Awon iwe na si wa lowo olorun.
Lehin eleyi ni motayi (iwe AlBadr Vol. 2 No. 6 1903: Mukashifaat P. 28-29). Ejeki awo awon nkan ti
owa ni oro ti Ogbeni Mirza so.
1. Alakoko, Olorun Oba je enikan ti oje abara osi nsise ni kotu pelu aga ati tabili.
2. Elekeji, enikan gege bi akowe ni lati ran Olorun lowo gege be awon adaja se nse.
3. Eleketa, ise tipoju fun Olorun nitorina ko aye lati da awon kan lohun.
Eje ka wonu Alukurani to sope: “Sa nafrogho ayohas saqalaan”. Laipe, awama ri aye lati koju si yin, eyin
Alijannu ati eyin eeyan. Sura Rahman sugbon nigabti Movi Muhammad Ali Sahib ti ilu Lahori Ahmadiyya
Jamaat ma salaye aro Kurani yi, oso wipe, lati, koju siyin nipoe lati jeyan ni ya. Nidi eyi lati koju si Mirza jepe
lati je ni ya fun ese tose sugbon, nigbati Mirza sope. Olorun ni ohun maa to raye koju si, nje olorun je ni ya
bi? Tabi odi dajo?
58 Mirza sahib tan ri iran pe:
Anta minee ba manzila tawheediee. Latodo mi loti wa, gege be eminikansoso (iwe haqeeqal-ul
wahi p. 86, Roohani Khazain Vol. 22 P. 89)
Eyi ore wa lati Ahmadi
Nigbati emo pe olorun kan soso ni. Ohun nika lowa. Lehin ti eti gbape olorun kan soso lo wa, eyin
na tungba pe oga, yin na okan ni ohun na, ti obaje be. Nje atunlesope olorun ko ni orogun bi.
59 Ogbeni Mirza se apeju we iriran re pe
Antaa minee ba manzilat waladee
Iwo wa lti odo gege bi omo mi
(Haqeeqat-ul-wahi p. 86, Roohani Khazain Vo. 22 P. 89)
(Iwe Albushra Vol. 2 p. 65)
Eyin omo leyin, Mirza, oga yin so wipe ohun da gegebi Alykwani ati pe awon nkan towa ni be ma
wa lati odo ohun. Ti e ba wo Alukuro Surah Maryam, Olorun sope ohun ko ni omo ati be be lo ti de
92. Se eyin na ripe Alukwani kojale pe olorun koni omo larin oro olorun ati oro oga yin, ewo ni ale
pe ni ododo ati eleyi toje awo, olorun ni ohun, olorun siso ninu Alukwani pe ohun ko bi mo.
60 Ogbeni Mirza to so wipe
Sirroka sirree: Ikoko re ni koko mi
Ninu awon oro wonyin ni “Olorun” ti so funnirza pe ino miza! Eni ati iwo ni ikankanna, ko si iyato
larin wa. Ninu esin Christianity, baba, omo ati enu mimo, meteta loje. Olorun kan sugbon mirza ko ti
aye sile fun aye keta. Olorun kan wa loke, ikan sokale ninu awon mirza gegebi bi agbara ti a fun
mirza. Olorun a sokale si oadian. (Albushra Vol 1. P. 56) sibe, ko si olorun meji aya fi eyokan nitori
wiwa mirza lati odo olorun ni
(a) Eko kanna ti mirza sahib se alaye ni eleyi “Mo ri ninu ala pe oun se dede pelu olorun mo de gbagbo
pe emi ni olorun, lai jepe ero mi duro lati enu kan… minu ipa mi (nigbati mo je olorun) mos so wipe.
A nfe asa ipin le mo da orun ati aiye ni apapo, lai si iyato ati eto. Lehinna mo wa pin won si ototo
pelu eto ati wipe lati igba yen in mo ti ara mi lati se gbogbo eleyi, Lehiina, mo koko da oju orun mo
de so inna zaiyanna assamaa adunya be maasaabeeha (A ti se awon orun to wa ni isale patapato
ni oso nith atupa 67:5) Lehinna ni mo tun so A wa da eniyan pelu iwon amo. Bayi mo da Adam, mo
si da Adam pelu apere to dajin mi idi eleyi mo di KHALIQ-ELEDA “ (Aina-e- kamalaat-e-islam P.
564 – 565: Roohani Khazain Vol. 5 P. 564-565).
Eyi ore Ahmadi! E so fun mi, e de so fun mi lotoro: Nje mirza sahib fi ikankan si le lati je olorun?
Mirza sahib so pe: oun gbagbo e oun gan ni olorun. Eleyi ni pharaoh so Ana Rabbokum al ala. E so
fun mi kin ni iyato ninu awon oro mejeji yi? Eyi ero iworan! Mirza sahib ko kan so wipe oun ni olorun
to da orun ati aiye, o tun so bayi “Won ti fun mi ni agbara ati pa emi pelu ati fun yan ni emi”.
(Khutba-e-llhamiyan p.23, Roohani Khazain vol. 16 P. 23) ninu ibomi, Mirza Sahib so ninu agbara
ohun pe “(Iwo mirza!) dajudaju, ase re ni. Ti o ba fe ikankan, wa so wipe: Jebe, a si sele (albushra
Vol. 2 p. 94)
Eleyi fi won pe Mirza sahib ni agabra “kun fa yakoon”. Agbara a ti fun yan ni emi pelu ati gba wa ni
owo mirza. Mirza sahib da oju orun tuntun ati aiye, o da Adam pelu ni siyi, eyin ore Ahmadi la ti so
fun mi pe ki o ku lati so ara re di olorun?
Eyi eroiworan! Ni soki ninu oro mi mo ti fi han yi gbogbo wa aiyagbo ti o tako esin Islam ati oro
Mirza. E ma je ko ya yi lenu pelu gbogbo ayimokoro oro yi. Otiti oro nipe olorun ti fun ni aye lati se
ikan ti o ba fe gegebi mirza se alaye ninu awon oro enu to nso. “Iwo Mirza! Se bo ba ti fe, mo ti da
ori ese re ji o, (Albadr Qadian vol. 3 No. 16, 17 p. 8)
Bayi nigbati olorun re ti yo gbogbo ihawo ofin shariah fun mirza, ko de si ero mi fun lati se wahala
boya Quran ati Hadith fi ara mo.
Eyi ore Ahmadi! Yato si oro Quran ati Hadith, oro Mirza sahib fi agbara mu mi lati ko sle awon iro
ati aise ododo ki nde wa fi ara mo ona otito ati ododo ti sunna ti ijo Islamd
MAULANA LAL HUSSEIN AKHTER
Mouvement Anti Ahmadiyya en Islam
Dr Syed Rashid Ali
P O BOX 11560
DIBBA al-FUJAIRAH
UNITED ARAB EMIRATES
email: rasyed@emirates.net.ae/ hltp ://alhafeez.org/Rashid/