iwe yii. Nje apeere wa wipe won yoo pa Lekhram? Ohun ti asotele n fihan ni agbara tabi ami to ju oye eda lo, iyanu ti ko lafiwe ati ami orun kii se nipa iku Lekhram. Nje iku Lekhram je atubotan isele oju lasan? Isele ti o wopo ni ki a gun eniyan lobe pa. A le ba apaniyan lowe nipa sisan owo oya/ise re fun-un. Nitori naa ki ni ohun ti o koja oye eniyan ninu ipaniyan yii? Ati wipe o ti wa ni akosile Mirza Ghulam ti o ti so pe.
“Ohun ti ko lafiwe, lona miran ewe a le pee ni khaariq-e- Aaadat.
Khaariz-e-Aaadat ni a ka si ohun ti ko ni ijora / afiwe lode aye yii.
Ohun to sele I wipe okunrin alagabagebe kan n dibon gege bi olufokansin kan wo aarin awon akekoo Lekhram o si n wa aiye, logan to ri pe Lekhram nikan da wa lo gun un pa ti o si na papa bora.
Iroyin wonyi ni a ri ninu iwe laka atigba-de-igba Ahmadiyyat lati karachi “ohun irahti”.
Ni ojo satide tii se ojo kefa, osu keta odun 1897 ni a sapejuwe pe pandit Lekhram wa ni ilaji ihoho ti o n gbadura sindhiya (bi o se n josin) ni yara oke. Leyin ti o josin tan, o fara lele nitori ikun re ti o tobi. Musulim ti o gba shudh (fari o si di Hindu) n joko nitori pelu aso to da bora. O gun Lekhram lobe nikun ti o fi je pe gbogbo ifun re tu sita.
Ohun ti Mirza Ghulam so nipa isele yii niyii. Ise owo awi ni a ti ri kedere ninu oro Lekhram. Wiwa eniyan sodo re pe ki o gba shudh, ti o si fokan tan eni naa debi pe o mu u wonu iyewu re, ti o pinya pelu awon alejo re lale, awon mejeeji lo ku sile, lojo keji Eid ni o si fe se ise yii, lojiji ti Lekhram dide nibi ti o ti n ko n kan ti o si na ara ati ikun re siwaju, obe oloju meji naa sise ijamba, titi di akoko iku re Olohun dee ni ahon ti o fi je wipe pelu gbogbo ogbon ati imo ti mo ti sotele fun un ko figba kan funra pe mo funra si Mirza Saheb, titi di oni owo ko te apaniyan naa gbogbo iwonyi ni ise Olohun eyi ti o n fi titobi ati agbara re han.
Awon onkawe ni lati ka awon akosile yii finnifinni. Bi Mirza Ghulam se gbe isele igba ikehin Lekhram, bi o ti le je pe o je ohun itiju, sibe a ri awon ibeere pataki, BAWO NI MIRZA GHULAM SE MO NIPA RE? BAWO si ni MIRZA GHULAM SE MO PE LOJIJI NI LEKHRAM DIDE NIBI TI O TI N KOWE. TI O NA ARA RE TI IKUN RE SI YO SITA ATI IGBA TI WON GUN-UN LOBE NIKUN? Eniyan meji pere lo mo nipa re; eni ti o paniyan ati eni ti won pa. Beeni Olohun (Allah) si mo nipa re bakan naa. Sugbon Mirza Ghulam ko figba kan so o ninu iwe re pe Olohun fi isele naa han ohn. Lekhram ko si laye mo lati wa so pato ohun to sel.
Eni ti o le so fun Mirza Ghulam ni okan ni apaniyan funrare.
Nje Ahmadi / Qadiani kankan le so fun wa irufe ibasepo to wa laarin Miza Ghulam ati apaniyan ti o mu iroyin wa si etigbo re? Ati wipe ki lo fa ti Mirza Ghulam ko le fi irufe eni onitohun sowo si awon olopaa? Ti apaniyan naa ko ba si lara awon omoleyin re, nigba naa n je o seese wipe agbanipa ni?
Nibi, oro mirza Ghulam miran tun fanimora:
Asotele onise eke ko lee wa si imuse laelae, Olohun dide sii ki iran eniyan ma ba dibaje gege bi Lekhran se fi ogbon arekereke aye polongo mi wipe emi yoo ku larin odun meta, ki ni se ti oun tikarare ko lee padi apo po mo apaniyan ki asotele ma baa se?
Oro yii fi han gbangba pe Mirza Ghulam mo bi o se le ri apaniyan lati pa enikeni.
Iwe iranti atigbadegba Ahmadiyya ko bayii pe:
Awon eniyan so wipe (iyawo ati iya Lekhram) so pe won ri apaniyan naa ti o sokale bo lati ategun Mirza Bashir Ahmad omo Mirza Ghulam ko bayii,
Gege bi oro iyawo Lekham ati bee bee lo, a gbo pe leyin ti o pa Lekham tan o gun oke o si wo inu aja ile lo.
Ibeere niyi: Ti o ba je pe moleka / angeeli lo pa Lekham bi Ahmadi se fe ki a gbagbo, ki lo de to fi dara po mo awon olusin ti o si wa aye lati pa Lekham, abi lehin ti o ti paa tan, ki ni idi ti o fi sokale ti o si tun goke pada? To ba tile je pe o wa gege bi aferi, iba ti pora mo inu yara nibe ambosi-bosi pe enikeni yo gan-an ni re . Tabi angeli / moleka le paniyan lairi niwaju gbogbo awon to n josin – awowi gbaa ni eyi
Eri to daju niwonyi, ti o si da awon olopaa agbegbe loju pe ote didi ati rikisi niyi eyi ti o je pe Mirza Ghulam lowo ninu re. Odindi igba meji gbako ni wonde ilee re, sugbon oun paapaa kii se ope.
Awon eniyan wonyi mo lokan ara won pe ise Olohun niyi ati pe kii se idimo eni to so asotele, sibe o tun pe ijoba ki won wa ye ile oun wo nipa idasile irokeke mimuse ijosin pelu awon to n bo maluu.
Lati ago olopaa won be ile re wo lojo kejo osu kerin odun 1897.
Owo ko te apaniyan naa, Bee ni ijoba oyinbo (British Government) ko ri ohunkohun se sii bikose yiye ile re wo lasan, pelu gbogbo atenumo awon Hindu. Won fenuko lati fedo lori ororoo fun ipinnu nla.
Awawi asan miran fun ise iyanu ti ko sele. Kin ni ere oku-opuro ju wipe ki orun fi ami han an ki aye si woran re?
Mirza Ghulam ko oro etan tikarare.
A gba itoni emi ati iru omoleyin, ti o buru ju aja ati igbe aye aimo awon maa so asotele nile, ati wipe pelu owo ara won ati pelu ogbon alumo-koroyi ati etan won gbiyanju pe won mu ti ara elomiran se
Ipe si yiyan Khalifa tuntun ti Jamaat Ahmadiyya, Mirza Masroor Ahmad.
A fi towotowo pe Khalifa karun –un Mirza Masroor Ahmadi Qadina, yala ki o wa siwaju tabi ki o se Mubahila pelu wa lori oro Lekhram bi bee ko yoo bura ( pelu ijiya latorun ti o ba bura eke ) pe Mirza Ghulam Ahmadi Qadiani ko lowo ninu iku Lekhram nitori iku re ko wa latodo eniyan kankan bikose lodo angeli / moleka, nipari wipe asotele Mirza Ghulam Ahmad Qadiani lo se.
Ibewo Ahmadi atijo, Ahteshamul Hag Abdulbari si Belgium laipe.
Olori awon Asodi si Ahmadiyya / Qadiani ni Mumbai India, be Belgium wo ni osu kejila odun 2003. Ni akoko ibewo yii won ri eni ti o sese gba Islam, eni ti o ti wa ninu igbekun latowo ijo ( jamaat) Ahmadiyya. Alhamdolillah nigba ti arakunrin Ahtesham salaye fun-un iru iwa Ahmadiyya n hugan-an o fi ijo naa sile leyin naa won pe e wa si gbongan ijo ni Anti –wep lati jiroro lori agbegbe Muballighs. Agbegbe Murabbi Nasir Ahmad Sindh soro nipa anfani awe gbigba lede oyinbo / geesi.
Ni opin oro re, niwaju gbogbo eniyan Atesham gbiyanju lati beere awon ibeere kan lori Mirza Ghulam Ahmad Qadiana, oludasile ijo itesiwaju Ahmadiyya, sugbon won daa duro, sugbon lehin eleyii, o ni anfani lati soro ni apejopo awon Ahmadi nipa awon oro Mirza Ghulam.Murabbi Nasir Ahmad Sindh soro fun awon Ahmadi yooku. Lara awon ti o pese nibe ni ogbeni Hashmi, Malik Naeem, Khalid Iqbal, Hafeezbutt saheb, Chaudhary Mansoor Ahmad siakoti ati awon yoku. Ni wa ju won Mubahila mu aye laarinAhtshan ati awon Ahmadi otito ati iro, won si so ni gbangba pe ki egun Olohun (Allah) wa sori awon opuro / oniro ni sido pe Laanatallah ala al kazibben
Arakunrin Ahtesham ro ogbeni murabbi ki o ba oun wa gbo iwe ti mirza Ghulam Ahmad ko pe oun yoo san saheb pinnu lati baa wa won sugbon o yi ipinnu re pada. Ni akoko isoro yi murabbi saheb ati ch. Mansoor se?
Ahmad Sialkoti binu repete won si bere si bura fun elesin Islam tuntun yii, won tile gbiyanju ati naa. Arakunrin Ahtesham ran won leti pe biba ara wa ja kii se ona ti a le fi waasu esin Islam. O si so fun won pe ti won ba de mosalasi awon musulumi iniruuru iwa ni won yoo ri.
Ki Olorun fun awon omoleyin Ahmadiyya won ni isiju lati mo otito yato si iro ati hidayah lati ri ona ti o to. Amin.
Wa maa alaina ila- albalaagh.
Wassalam ala mum- ittaba’a al-huda.
Dokita Syed Rashid Ali.